English - Yorùbá Dictionary

May

Maybe adv. /  bóyá.

Mayor noun. /  onídájọ́ ìlú, olórí ìlú.

Me pron. /  mi, èmi.

Meadow noun. /  pápá oko tútù.

Meal noun. /  onjẹ, ìyẹ̀fún.

Mean adj. /  ènìyàn lásán, láìnílárí.

Meaning noun. /  ìdí ìtumọ̀.

Meaningful adj. /  tí ó nílàrì, tí ó níyìn.

Meaningless adj. /  ìtumọ̀lásán.

Meantime adv. /  níbáyí, lákókòyí, nísìsìyí.

Measure verb. /  wọ̀n. verb. / ìwọ̀n.

Measurement noun. /  wíwọ̀n.

Meat noun. /  ẹran jíjẹ.

Media noun. /  àwọn oníròhìn.

Mediate verb. /  làjà, bá làjà, wà láàríín.

Medical adj. /  ti ògùn.

Medicine noun. /  ògùn, egbògi.

Meditate verb. /  ṣe àṣàrò, ronú, gbìrò.

Med

Meditation noun. /  ìṣàrò.

Medium noun. /  árín.

Meet verb. /  pàdé, kò lójú.

Meeting noun. /  ìkòlójú, ìpàdé.

Melt verb. /  yọ́.

Member noun. /  èrò inú ẹgbẹ́.

Membership noun. /  jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́.

Memorial noun. /  ohun ìrántí.

Memory noun. /  iyè inú.

Mend verb. /  tún ṣe.

Mention verb. /  se ìrántí, dá-orúkọ. noun. / ìrántí, ìdárúkọ.

Menu noun. /  ìwé ètò onjẹ.

Merchandise noun. /  ọjà títà.

Merchant noun. /  onísòwò.

Mercy noun. /  àánú, ìyọ́nú.

Merge verb. /  bọ sínú.

Merger noun. /  ìbọ́sínú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba