English - Yorùbá Dictionary

Mer

Merit noun. /  èrè, ìtọ́sí.

Mermaid noun. /  yemọja.

Merry adj. /  inú dídùn.

Message noun. /  iṣẹ́ rírán, ọ̀rọ̀.

Messenger noun. /  ìránsẹ́, òjísẹ́, onsẹ.

Messy adj. /  wúruwùru, láìlẹ́tò.

Method noun. /  ìlànà, ìwà ìtò lẹ́ṣẹṣẹ.

Mettle noun. /  ìgboyà.

Middle adj. /  lárín, lágbedeméjì. noun. / árín, agbedeméjì.

Midnight noun. /  ọ̀gànjọ́, óru, àjin.

Midway noun. /  ágbedeméjì ọ̀na.

Might noun. /  agbára, ipá.

Mighty adj. /  alágbára.

Migrate verb. /  ṣí láti ibí kan lọ sí ibòmíràn.

Mile noun. /  ìbùsọ̀, ìwọn ọnà.

Military adj. /  ti ogun. noun. / ológun.

Mill noun. /  ọlọ, ẹrọ. verb. / lọ.

Mind noun. /  iyèinú.

Mine

Mine prop. /  tèmi.

Minimum  noun. /  kíkéré pátápátá, èyí tí ó kéré jùlọ.

Minister noun. /  ìránṣẹ́, òjíṣẹ́, àlùfáà.

Minority noun. /  kíkéré, àkókò èwe.

Minus prep. /  yọ kúrò, dínkù.

Minute noun. /  ìṣẹ́jú.

Miracle noun. /  iṣẹ́ ìyanu.

Mirror noun. /  díngí.

Misconduct noun. /  àìmọwàhù, ìwà-àìtọ, ìwà-àìyẹ.

Miserable adj. /  láìní àlàáfíà, àbòsì.

Misery noun. /  òsì, ìrora ara, ìrora ọkàn.

Misfit noun. /  laibamu.

Misinterpret verb. /  sì túmọ̀.

Misleading adj. /  sísì lọ́nà.

Misplace verb. /  fi sípò tí kò tọ, fi sí ibòmíràn.

Misprint verb. /  ṣi tẹ.

Miss verb. /  tàsé, pẹ, ṣì, fẹ kù.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba