English - Yorùbá Dictionary

Miss

Missing adj. /  fẹ kù, láìpé, nù.

Mission noun. /  iṣẹ́ pàtàkì.

Missionary noun. /  ìránsẹ́, onísẹ́ Ọlọ́run.

Mistake noun. /  àṣìṣe.

Misunderstand verb. /  ṣi mọ, ṣì yé, sàìyé.

Misunderstanding noun. /  èdè-àiyedè, gbólóhùn-aṣọ̀.

Misuse verb. /  lò nílòkulò, lò sódì, sìlò.

Mix verb. /  papọ, dàpọ, lúpọ̀.

Mixture noun. /  àdàpọ̀, àdàlù.

Moan noun. /  ìkérora, gbígbin. verb. / sukún, kérora.

Mobile adj. /  tí ó lè yípò padà.

Mobility noun. /  yíyí pòpadà.

Mobilize verb. /  gbé dìde.

Moderate adj. /  níwọ̀ntúnwọ̀nsí.

Modern adj. /  ti ìgbà ayé òde òní.

Modernize verb. /  sọ́di ti ìgbà ayé òní.

Modification noun. /  ìyípadà, àtúnṣe.

Modify verb. /  yípadà. túnṣe.

Moi

Moist adj. /  tutù.

Moisture noun. /  ọ̀rinrin, ìtùtù.

Mole noun. /  kúlúsọ.

Moment noun. /  àsìkò, ìsẹ́jú kan.

Money noun. /  owó.

Money order noun. /  ìwé owó.

Monitor verb. /  bójútó.

Monkey noun. /  ọbọ, ìjímèrè.

Monster noun. /  ohun ìbanilẹ́rù.

Month noun. /  oṣù.

Monthly adj. /  loṣoṣù.

Monument noun. /  ìbòji, ohun ìrántí.

Mood noun. /  ìwà inú.

Mop noun. /  ìnulẹ̀.

Moral adj. /  ìwà rere.

More adj. /  si, jùlọ, síwájú.

Morning noun. /  òwúrọ̀, àrọ, ìdájí.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba