English - Yorùbá Dictionary

Mor

Mortar noun. /  odó.

Mortuary noun. /  ilé ìpamọ́ òkú.

Mosque noun. /  mọsálásí.

Mosquito noun. /  ẹfọn.

Most adv. /  jùlọ, rékọjá, tí ó pọ jùlọ.

Moth noun. /  àfòpiná, èlá.

Mother noun. /  ìyá, abiyamọ.

Mother in law noun. /  àna ìyá ọkọ tàbí àna ìyá ìyàwó.

Motherly adj. /  ìwà bi ti ìyá.

Motion noun. /  ìsípòpadà, ìpinnu, àbá.

Motionless adj. /  duro láìmira, dúró gbagidi .

Motivate verb. /  gbà ní yànjú, sí-lórí.

Motivated adj. /  oníyànjú.

Motivation noun. /  ìyànjú, ìwúrí.

Motive noun. /  ìdí, èrò, ohun tí ó mú kí a se nkan.

Motorist noun. /  awakọ̀.

Motorway noun. /  títì, ọnà, òpópó.

Mountain noun. /  òkè gíga.

Mou

Mourn verb. /  sọ̀fọ̀, banújẹ́.

Mourner noun. /  aṣọ̀fọ̀.

Mouse noun. /  èkúté.

Mouth noun. /  ẹnu.

Movable adj. /  ohun ti a le gbé kiri.

Move verb. /  rìn, ṣípò padà.

Movement noun. /  ìrìn.

Mow verb. /  gé, rẹ.

Much adv. /  púpọ̀, pípọ̀.

Muck noun. /  èérí, ẹrẹ̀.

Mud noun. /  pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀.

Muffler noun. /  ìborùn.

Mugging noun. /  ìjàlólè, gbà ní tipátipá.

Mulatto noun. /  ọmọ ti ènìyàn dúdú àti funfun jọ bí.

Mule noun. /  ìbaka.

Multiple adj. /  lílọpo.

Multiply verb. /  se ní ìlọpo ìlọpo.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba