English - Yorùbá Dictionary

Mur

Murder noun. /  ìpànìyàn.

Murderer noun. /  apànìyàn.

Murky adj. /  ṣu, ṣókùnkùn.

Murmur noun. /  kùn sínú, ráhùn.

Muscle noun. /  isan.

Museum noun. /  ilé àkójọpọ̀ ohun àtàtà àti ohun lailai.

Mushroom noun. /  olú.

Music noun. /  orin.

Musical adj. /  ti orin.

Musician noun. /  olórin.

Musk noun. /  ẹtà.

Musket noun. /  ìbọn.

Muslin noun. /  aṣọ fẹlẹfẹlẹ.

Must verb. /  aigbọdọ má se, gbọdọ̀ se ní dandan.

Mustache noun. /  irun imu ọkùnrin.

Mustard noun. /  ewéko.

Muster noun. /  àgbájọ, àkójọpọ̀.

Musty adj. /  bíbàjẹ́.

Mut

Mutable adj. /  tí a lè yípadà.

Mute adj. /  dákẹ́.

Mutilate verb. /  ge apákan jùnù.

Mutiny noun. /  ọ̀tẹ̀. verb. / ṣọ̀tẹ̀.

Mutter verb. /  kùn.

Mutton noun. /  ẹran àgùtàn.

Mutual adj. / alábàpín nípa gbígbà àti fífún, ni ti òtún tòsì.

Muzzle verb. /  dì ní ẹnu, mu dákẹ́.

My pron. /  tèmi, mi.

Myriad noun. /  aimoye, ọ̀pọ̀lọpọ̀.

Myself pron. /  èmi gangan.

Mysterious adj. /  ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀, jíju ìmọ lọ.

Mystery noun. /  àràmàdà, àwámáridì.

Mystic adj. /  ohun ìjìnlẹ̀, ni àsírí.

Mystify verb. /  lumọ́, fi su lójú.

Myth noun. /  àlọ, ìtàn lásán, àròso.

Mythology noun. /  ẹ̀kọ́ nípa àròsọ.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba