HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Nag
Nag
verb.
/ yọ lẹ́nu, mu bínú.
Nail
noun.
/ ìṣó.
Naked
adj.
/ níhòhò.
Name
noun.
/ orúkọ.
Nap
noun.
/ ògbé.
verb.
/ tògbé.
Napkin
verb.
/ aṣọ ìnuwọ́.
Narration
noun.
/ ìhìn, ìròhìn, ìtàn.
Narrow
adj.
/ tóró, híhá, há.
Nasal
adj.
/ ti imú.
Nasty
adj.
/ lérí, lẹ́gbin, korò.
Nation
noun.
/ orílẹ̀ èdè.
National
adj.
/ ti orílẹ̀ èdè.
Nationality
noun.
/ ará ìlú, ìlú.
Native
adj.
/ ti ìbí, onílẹ̀.
noun.
/ ọmọ ìbílẹ̀, ará ìlú.
Natural
adj.
/ adánidá, ti ìwà ẹ̀dá.
Naturally
adv.
/ tinú-tinú, láìfagbárase.
Nature
noun.
/ ìwà, ẹ̀dá ohunkóhun.
Naughty
adj.
/ búburú, ṣaigboran.
Nav
Navel
noun.
/ ìwọ́, ìdodo.
Navigate
verb.
/ tukọ̀, wa ọkọ̀.
Navigation
noun.
/ ìtukọ̀ lójú omi.
Nay
adv.
/ bẹkọ, àgbẹdọ̀, ewọ̀.
Near
adj.
/ nítòsí, súnmọ́ra.
Nearly
adv.
/ fẹ́rẹ̀, kù díẹ.
Neat
adj.
/ mọ́tónítóní, já fáfá, afínjú.
Necessary
noun.
/ nkan tí a kò le ṣe alaiṣe.
Necessity
noun.
/ àìgbọdọ̀ máṣe, ọ̀ranyàn.
Neck
noun.
/ ọrùn, ẹ̀mí.
Need
verb.
/ ní lò, fẹ.
noun.
/ àìní, àìtó.
Needle
noun.
/ abẹ́rẹ́.
Needless
adj.
/ láìnílárí.
Needy
adj.
/ aláìní, òtòsì, tálákà.
Negative
adj.
/ ọ̀rọ ìyàn, ọ̀rọ òdì.
Neglect
noun.
/ ìgbàgbé, àìbìkítà.
verb.
/ se ìgbàgbé.
Negligence
noun.
/ ìwà àìfiyèsí, ìjáfara.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.