English - Yorùbá Dictionary

Acc

Accessory noun. / èròjà.

Accident noun. / jàmbá, àgábkò, àdébá.

Accidentally adj. / láìròtẹ́lẹ̀, ṣàgbákò.

Accomodate verb. / fún láyè.

Accomodation noun. / ilé gbígbé,àyè.

Accompaniment noun. / ìbánikẹ́gbẹ́, àjọrìnpọ̀.

Accompany verb. / bá-lọ, bá-rìn, bá-kẹ́gbẹ́.

Accomplice noun. /  ẹlẹ́gbẹ́ ìwà búburú.

Accomplish verb. / ṣe-parí, ṣe-tán, ṣe àṣepé .

Accomplishment noun. / àṣetán, ìṣeparí, ìṣepé.

Accord verb. / bá rẹ́.

Accordance noun. / ìbárẹ́, ìṣọ̀kan.

According prep. / bí, gẹ́gẹ́bí.

Accordingly adv. / nítorínà.

Accost verb. / tètè kí, tètè bá sọ̀rọ̀.

Account noun. / ìṣirò, ìkàsí, owó àpamó.

Accountant noun. / onísirò, akọ̀wé owó.

Accumulate verb. / kó-ja, dálé.

Acc

Accumulation noun. / ìkójọpò ,àdálé,àkànmọ́.

Accuracy noun. / ìṣegẹ́gẹ́, ìṣedédé.

Accurate adj. / dédé, pé ṣánsán.

Accusation noun. / ìbáwí,ẹ̀sùn,ìfisùn.

Accuse verb. / fisùn, kà sí lórùn.

Acccuser noun. / olùfísùn.

Ache noun. / fífọ́, ríro.

Achieve verb. / ṣe tán, ṣe parí.

Acid adj. / kan, kíkan, mú.

Acidity noun. / kikan, mímu.

Acknowledge verb. / jẹ́wọ́, gbà.

Acknowledgment noun. / ìjẹ́wọ́, gbígbà.

Acquaint verb. / fi hàn, sọ fún,

Acquaintance noun. / ifíhàn, ojúlùmọ̀.

Acquiesce verb. / gbà, dákẹ, fi arabàlẹ̀.

Acquiescence noun. / gbigbà, idákẹ,ìfarabálẹ̀.

Acquire verb. / jèrè, dé ibẹ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba