English - Yorùbá Dictionary

Acq

Acquisition noun. / ohun ìní, èrè.

Acquit verb. / dásílẹ̀, jọ̀-lọ́wọ́, dá-láre.

Acquittal noun. / ìdásílẹ̀, ìjọ̀lọ́wọ́, ìdáláre .

Acrobat noun. / eléré ìtàkìtì, alágèéré.

Acrobatic noun. / eré ìtàkìtì.

Across prep. / láti ẹ̀gbẹ́ kan dé èkejì,rékọjá lórí,.

Act noun(action). / ìṣe,òfin.

Act verb(play). /  seré.

Action noun. / ìṣe, ìwà,ìpèlẹ́jọ́.

Active adj. / yára, nítara.

Activist noun. / alámúṣe.

Activity noun. / àmúṣéṣe,ìyára,akán.

Actor noun. / òṣère ọkùrin.

Actress noun. / òṣère obìnrin.

Actual adj. /  gangan,nítotọ́.

Actually adv. / nítòótọ́,pàápàá, gan-an.

Acupuncture noun. / ìfi abẹ́rẹ́ gún ní lára.

Acute adj. / mímú le, lóró.

Adamant

Adamant adj. / lórí-kunkun, ní dandan.

Adapt verb. / mú yẹ,mú bád ọgba.

Adaptable adj. / ní mímúyẹ.

Adapter noun. / alámúyẹ.

Add verb. / ròpọ̀, fikún, fi sí,bùkún, bùsí.

Addict noun. / ẹnití o fọ́ràn nkan láfèẹ́jù.

Addiction noun. / àfẹ́sódì.

Addition noun. / àròpọ̀, ìfikún, ìròpọ̀.

Additional adj. / àfikún, ríròpọ̀.

Address noun. / ibi ìkọ̀wé sí.

Address verb. / bá sọ̀rọ̀.

Adept noun. / ọlọ́gbọ́n.

Adequate adj. / tó fún

Adhesive adj. / ohun tí a lè fi lẹ nkan.

Adhere verb. / fara mọ́, somọ́, lẹ̀mọ́.

Adherence noun. /  ìfara mọ́, ìsomọ́, lílẹ̀mọ́.

Adhesively verb. / tímọ́tímọ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba