English - Yorùbá Dictionary

Any

Anyhow adv. /  lọ́nàkọnà, bákan, níṣekúṣe.

Any-one noun. /  èyíkèyí, ẹnikéni.

Anything pron. /  ohunkóhun.

Anytime adv. /  nígbàkúgbà.

Anyway adv. /  lọ́nàkọnà.

Anywhere adv. /  ibikíbi.

Apace adv. /  kíakía, yárayára.

Apart adv. /  lápákan, sọ́tọ̀, géde.

Apartment noun. /  yàrá, ìyẹ̀wù.

Apathy noun. /  aìbíkítà.

Ape noun. /  ọbọ ,ẹdun, akítì.

Apex noun. /  ṣónṣo.

Apologize verb. /  bẹ̀bẹ̀, ṣìpẹ-fun, tuba.

Apology noun. / ìtọrọ àforíjì.

Appal verb. /  dẹ́rùbà, jálaiyà.

Apparatus noun. /  ohun èlò.

Apparent adj. /  hàn gbángbá.

Apparition noun. /  ìfarahàn.

Appeal

Appeal noun. /  ìfilọ̀, ibère, ẹ̀bẹ̀, ẹjọ́ àpétúnpè.

Appeal verb. /  fi ọ̀ràn lọ̀, bẹ̀bẹ̀ .

Appear verb. /  hàn, farahàn yọjáde, yọjú.

Appearance noun. /  ìfarahàn, ìyọjáde.

Appease verb. /  tù-nínu, ṣìpẹ̀-fún, pẹ̀tù-si .

Appellation noun. /  orúkọ, oríkì.

Append verb. /  fi kọ́, so mọ́, fimọ́, fíkún.

Appendage noun. /  ìfikọ́, ìsomọ́,ìfimọ́, ìfikún.

Appetite noun. /  ebi pipa, ìfẹ́ láti jẹun.

Applause noun. /  ìyìn.

Appliance noun. /  ohun èlò.

Applicant noun. /  ẹnití ó bère fún nkan .

Application noun. /  ìfokànsí, ìfisí, ìbèrè fún nkan.

Apply verb. /  filọ̀,bèrè fún.

Appoint verb. /  yàn, yà sọ́tọ̀, pinnu.

Appointment noun. /  ìpinnu, ìpàdé,yíyàn.

Appreciate verb. /  mọyì, mọ rírì.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba