English - Yorùbá Dictionary

App

Apprehend verb. /  dì mú, gbá mu, bẹ̀rù,fòiyà.

Apprehension noun. /  ìbẹ̀rù, ìdìmú.

Apprentice noun. /  ọmọiṣẹ́,ẹnití nkọ́ṣẹ́.

Apprenticeship noun. /  ìgbà ìkọ́sẹ́.

Apprise verb. /  sọ fún.

Approach noun. /  ìsúnmọ́. verb / súnmọ́.

Approbation noun. /  ìdùnmọ́, inú dídùn sí.

Approval noun. /  ìfohùnsí, ìlóhùnsí, ìdúnwò.

April noun. /  oṣù kẹrin ọdún.

Apron noun. /  bàntẹ́, tòbí.

Apt adj. /  yẹ, múra.

Aptitude noun. /  yiyẹ, imúra.

Aquarium noun. /  ilé ìtọ́jú àwọn ẹja.

Arab noun. /  lárúbáwá.

Arabic noun. /  èdè lárúbáwá.

Arbiter noun. /  onídajọ́, onílàjà.

Arc noun. /  apákan àyíká.

Arch adj. /  bìrìkìtì.

Archer

Archer noun. /  tafàtafà, ọlọ́fà.

Archery noun. /  ọfà.

Architect noun. /  ayàwòrán ilé.

Architecture noun. /  ilé kíkọ́.

Archway noun. /  ẹnu ọ̀nà ìwọ̀lú.

Area noun. /  agbègbè ilẹ̀.

Arena noun. /  gbagede eré.

Argue verb. /  jiyàn.

Argument noun. /  ìjiyàn, ìṣàròyé, iyàn-jíjà.

Argumentative adj. /  jíjiyàn.

Arise verb. /  dìde, yọjáde, farahàn.

Arithmetic noun. /  ẹ̀kọ́ ìsirò,ìsirò owó.

Arm noun. /  apá. verb hámọra

Armpit noun. /  abíyá.

Arms noun. /  ohun èlò ogun.

Army noun. /  ọmọ ogun.

Around prep. /  yíkákiri.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba