English - Yorùbá Dictionary

Ang

Anger noun. /  ìbínú, írúnú.

Angle noun. /  ìwọ̀ apẹja, igun.

Angler noun. /  apẹja.

Angry adj. /  bínú, mú bínú.

Anguish noun. /  ìrora, àròkàn, àròdùn .

Animal noun. /  ẹranko.

Animate verb. /  ìdárayá.

Animation noun. /  dìdárayá.

Ankle noun. /  kókósè, ọrùn-ẹsẹ̀.

Anklet noun. /  ohun ọ̀sọ́ kókósè.

Annex verb. /  sómọ, dàpọ̀, fímọ́.

Annexation noun. /  ìfikún, ìsọpọ̀mọ́, ìdàpọ̀mọ́.

Anniversary noun. /  àjọ̀dún, àyájọ́.

Announce verb. /  kéde, filọ̀ ,sọ nígbangba.

Announcement noun. /  ìkéde, ìfilọ̀ .

Announcer noun. /  akéde.

Annoy verb. /  tọ́,yọ lẹ́nu,kọ́ loro.

Annoyance noun. /  ìmúbínú, ìyọnu.

Annoying

Annoying adj. /  dídánúbí.

Annual adj. / lọ́dọdún .

Annul verb. /  pa-rẹ́, mú kúrò,sọ di òfo.

Annulment noun. /  píparẹ́, ìpatì, ìparẹ́.

Anonymous adj. /  láìlórúkọ .

Another adj. /  òmíràn.

Answer noun. /  ìdáhùn, ìfèsì, èsì.

Answer verb. /  dá lóhùn, fèsì.

Ant noun. /  èrà, erùn.

Antelope noun. /  èsúró, ẹtu.

Antenatal adj. /  ṣájú ìbí.

Antidote noun. /  aporó, ẹ̀pa, apàgùn .

Antimony noun. /  tiro.

Anxiety noun. /  ájò, àníyàn, aibalẹ ọkàn, hílà-hílo.

Anxious adj. /  ṣájò, ṣàníyàn.

Any adj. /  èyíkèyí.

Anybody noun. /  ẹnikéni.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba