English - Yorùbá Dictionary

Arr

Arrange verb. /  tò lẹ́sẹsẹ, fi sí ètò.

Arrangement noun. /  ètò lẹ́sẹsẹ, ìfisí ètò.

Arrear noun. /  tẹ̀hìn.

Arrest noun. /  ìdádúró. verb / dádúró, dilọwọ.

Arrival noun. /  dídé, atidé, bíb ọ̀, àbọ.

Arrive verb. /  dé, bọ̀, ìpadàbọ̀.

Arrogance noun. /  ìgberaga, ìrera.

Arrogant adv. /  gbéraga.

Arrow noun. /  ọfà.

Arsenal noun. /  ilé ìpamọ́ ohun ìjagun lọ́pọ̀lọpọ̀.

Arson noun. /  fífilé jóná,ìtinábọlé.

Article noun. /  nkan, ohun kan.

Artifice noun. /  ọgbọ́nkọ́gbọ́n, ọgbọ́n àrékérekè.

Artificer noun. /  oníṣọ̀nà.

Artillery noun. /  ìbọn nlá.

Artisan noun. /  ọlọ́nà.

Artist noun / f. /  ẹnití nyà àwòrán.

Artist noun / m. /  ẹnití nyà àwòrán.

As

As prep. /  gẹ́gẹ́bí, bi o ti jẹ pé.

Ascend verb. /  gòkè, gùn, pọ́n.

Ascent noun. /  igun òke, ibi gíga.

Ashamed adj. /  tijú, ki ènìyàn jẹ̀bi.

Ashes noun. /  eérú.

Aside adv. /  lẹ́gbẹ kan.

Ask verb. /  bère, tọrọ,bi lerè.

Asleep adv. /  sùn,rẹjú, lojú orun.

Aspiration noun. /  ìfẹ́ ọkàn, inọga si.

Aspire verb. /  dáwóle,nọ̀ga si, lépa.

Assassin noun. /  apànìyàn.

Assassinate verb. /  lunipa, pa.

Assemble verb. /  pé jọ, kojọ,gbajọ.

Assembly noun. /  àpèjọ.

Assign verb. /  yan sílẹ̀, fi lélọ́wọ́.

Assignment noun. /  iyansílẹ̀, ìfilelọ́wọ́.

Assist verb. /  ràn lọwọ.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba