English - Yorùbá Dictionary

Ass

Assistance noun. /  ìrànlọ́wọ́.

Assistant noun. /  olùrànlọ́wọ́, aran-nilọ́wọ́.

Associate noun. /  ẹgbẹ́, ẹlẹ́gbẹ́. verb / dara-pọ̀mọ, bálò.

Association noun. /  ẹgbẹ́, ìbálòpọ̀.

Assorted verb. /  ìyàsọ́tọ̀.

Assurance noun. /  ìdánilójú, ìgbẹ́kẹ̀lé.

Assure verb. /  sodájú, múdájú.

Asterisk noun. /  àmì àkíyèsí.

Asthma noun. /  ik ọ́-fe.

Astonish verb. /  yàlẹ́nu.

Astray adv. /  kúrò lójú ọ̀nà, ṣìnà, yapa.

Astronomer noun. /  amòye nípa àwọn ìràwọ̀.

Astronomy noun. /  ẹ̀kọ́ nípa àwọn ìràwọ̀.

Asylum noun. /  ilé ìwòsàn àwọn asínwín tàbí adẹ́tẹ̀.

Asylum noun. /  ibi àbò fún ẹnití o sa kúrò ní orílẹ̀ èdè rẹ̀.

At prep. /  ní, níbí, lí.

Atheism noun. /  ẹ̀kọ́ àìgbàgbọ́ pé ọlọ́run nbẹ.

Atheist noun. /  àìgbàgbọ́ pé ọlọ́run nbẹ.

Athlete

Athlete noun. /  oníjàkadì, ẹnití nsáré ìje.

Athletics noun. /  íjàkadì, eré ìje.

Atlas noun. /  àwòràn ayé.

Atmosphere noun. /  àyíká.

Attach verb. /  so-mọ, fimọ.

Attack verb. /  kọ lù, dojúkọ́, fún nìjà.

Attempt noun. /  ìgbìyàjú, ìdánwò.

Attend verb. /  fiyèsí, dúrótì, dúrodè.

Attendance noun. /  ìfiyèsí, ìdúrótì, ìfetísílẹ̀.

Attendant noun. /  onítọjú, ọmọ ọ̀dọ̀.

Attention noun. /  ìfojúsí, ìfetísílẹ̀, ìfarabalẹ̀.

Attentive adj. /  ìfetísí.

Attest verb. /  jẹ́rìí sí.

Attitude noun. /  ìwà wíwù, ìsesí, ìdúró sí.

Attorney noun. /  agbẹjọ́rò, aṣojú ẹni lábẹ́ òfin.

Attract verb. /  fà mọ́ra, fà lọ́kàn.

Attractive adj. /  dára láti wò, tí ó wuni.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba