English - Yorùbá Dictionary

Adj

Adieu adv. / ọ̀nà're, ódígbòṣe.

Adjacent adj. / nítòsí, lágbègbè.lẹ́ẹ̀bá.

Adjective noun. / ọ̀rọ̀ àpéjúwe .

Adjourn verb. / sísún ìpàdé síwájú, yíyẹ̀ sí àkókò míràn.

Adjudge verb. / dájọ́-fun, dalẹ́jọ́, yán fún.

Adjust verb. / tún-ṣe, tò lẹ́sẹsẹ.

Adjustable adj. / títò lẹ́sẹsẹ, títún ṣe.

Adjustment noun. / ìtúnṣe, ìtòlẹ́sẹsẹ.

Administer verb. / ṣe ìpínfúnni, pín fún.

Administration noun. / ìpínfúnni.

Administrator noun(f/m). / olùpínfúnni, olùtọ́jú.

Admirable adj. / níyìn, yani-lẹ́nu,tayọ.

Admiral noun. / olórí ọkọ̀ ojú omi, olórí ọkọ̀ ogun.

Admiration noun. / ìyìn, ìjọ ni-lójú,ìyani-lẹ́nu.

Admire verb. /  yìn, jọ ni òjú, yani-lẹ́nu.

Admirer noun. / olùfẹ́ni,ayinni,ẹniti a jo lójú .

Admission noun(confession). / jíjẹ́wọ́, gbigba.

Admission noun(entrance). / ìwọ lé, ìgbàsílẹ̀.

Admit

Admit verb. / gbà sílé,gbà wọle, ìjẹ́wọ.

Admittance noun. / ìgbàsílẹ̀, ìwọlé .

Admix verb. / dá lu.

Admixture noun. / idálu.

Admonish verb. / kìlọ̀, ba wí.

Admonition noun. / ìkìlọ̀, ìbáwí, ìṣíléti.

Adolescence noun. / ìgbà ọ̀dọ́,ìgbà èwe.

Adopt verb. / sọ́dọmọ, gbà , fi se ọmọ.

Adopted adj. / sọ́dọmọ.

Adoption noun. / ìsọ́dọmọ.

Adorable adj. / ìbu ọlá fún,ìjúbà .

Adoration noun. / ìbọlá fún,ìyìn lógo.

Adore verb. / júbà, bu ọlá fún,yìn lógo,fẹ́ràn púpọ̀.

Adorn verb. / ṣé lọ̀sọ́,ṣe lóge.

Adornment noun. / ọ̀ṣọ́.

Adrift adv. / gbá lọ, gbá kiri.

Adroit adj. / gbọ́n, mọ́ ṣe.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba