English - Yorùbá Dictionary

Adv

Adult noun or adj. / àgbà, àgbàlágbà.

Adulterate verb. / lú, bàjẹ́, ṣèdàrú-dapọ̀.

Adulterer noun. / panṣágà ọkunrin.

Adulteress noun. / panṣágà obinrin .

Adultery noun. / ìwà àgbèrè, ìwà panṣágà.

Advance verb. / tẹ-síwájú, lọ-síwájú,gbéga.

Advanced adj. / ìtẹ-síwájú, ìlọ-síwájú.

Advancement noun. / títẹ̀síwájú.

Advantage noun. / anfàni, ìrọ̀rùn, èrè, ìfà.

Advantegeous adj. / rọ rùn, ṣanfàní, lérè.

Advent noun. / bíbọ̀, wíwá, dídé.

Adventure noun. / ìrìn akọ.

Adventurer noun. / adágbà, àdáwọ́lé.

Adverb noun. / ọ̀rọ̀ àpónlé.

Adversary noun. /  ọ̀tá, olódì.

Adverse adj. / lòdìsí.

Adversity noun. / ìpọ́njú, wàhálà, ìsẹ́, jàmbá.

Advertise verb. / polówó, ròhìn, sọfún, kéde.

Advertisement

Advertisement noun. / ìpolówó, ìròhìn, ìsọfún, ìkéde.

Advertiser noun. / apolówó ọjà.

Advertising noun. / pípolówó, kíkéde.

Advice noun. / ìmọ̀ràn, ìfọ̀nàhàn.

Advisable adj. / yẹ ni sísé.

Advise verb. / kọ́, fọ̀nàhán, ṣiníyè.

Adviser noun. / olùkọ́, olùfọ̀nàhán, onímọ̀ràn, ọlọ́rọ̀-ẹni.

Advocacy noun. / ìgbàsọ, ìgbàwí.

Advocate verb. / gbàwí,gbàsọ, gbèjà.

Aeroplane noun. / ọkọ̀ òfúrufú.

Affect verb. / mú lọkàn, wúlórí, kàn.

Affected adj. / ìmúlọkàn, ìwúlórí, kíkàn.

Affection noun. / ìfẹ́, ìwúrí.

Affectionate adj. / ní ìfẹ́, kún fún ìfẹ́.

Affiance noun. / ìgbẹ́kẹ̀lé , ìgbéyàwó.

Affidavit noun. / ìbúra lórí ìwé.

Affiliate verb. / sọ́pọ̀mọ.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba