English - Yorùbá Dictionary

Aff

Affinity noun. / ìbádàna, ìṣe-tímọ́tímọ́.

Affirm verb. / tẹ́numọ́.

Affirmation noun. / ìtẹ́numọ́.

Affix verb. / fi mọ́, so mọ́ lẹ́hìn, lẹ̀mọ́ .

Afflict verb. / pọ́n lójú, jẹ́ níyà, yọ́-lẹ́nu.

Affliction noun. / ìpọ́njú, ìjìyà, ìdálóró.

Affluence noun. / ọrọ̀, ọ̀pọ̀.

Affluent adj. / ọlọ́rọ̀, ọ̀pọ̀.

Afford verb. / ṣe, fún, náwó, ní agbára láti ṣe nkan.

Afloat adv. / fó lójú omi, lófo.

Afoot adj. / lẹ́sẹ̀.

Afore adv. / níwájú, ṣájú.

Afraid adj. / bẹ̀rù , fòyà.

Afresh adv. / lọ́tun, nítitun.

After prep. /  tẹ̀lé, lẹ́hìn.

After-birth noun. / lẹ̀hìn ìbí (ọmọ).

Afternoon noun. / ọ̀sán, ọjọ́rọ̀, ìrọ̀lẹ́.

Afterward adv. / nígbẹ́hìn, lẹ́hìn ná.

Again

Again adv. /  lẹ́kèejì, lẹ́kànsi.

Against prep. / lòdìsí, dojúkọ.

Age noun. / àkókò,ìgbà, ọjọ́ orí.

Agency noun. /  ìṣojú ẹni.

Agent noun. / aṣojú ẹni, àgàbṣe, aṣelédeni.

Aggrandize verb. /  sọ́di nla, gbé ga.

Aggrandizement noun. /  ìgbéga, ìsọ́di'nla.

Aggravate verb. /  dánúbí,bí-nínú.

Aggravating adj. / dídánúbí.

Aggravation noun. / ídánúbí, ìmúbínú.

Aggregate verb. / kójọpọ̀.

Aggress verb. /  fínràn, wá ìjà, tọ́.

Aggression noun. / ìfínràn, wíwá-ìjà.

Aggressive adj. / ìwà ìfínràn, ìwà títọni.

Aggressor noun. /  òfínràn, olùwájà.

Agitate verb. / rú sókè, mì, sọ̀rọ̀ lé lórí.

Agitation noun. / mímì , ìrú sókè , rúgúdù.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba