English - Yorùbá Dictionary

Agi

Agitator noun. / adárúgúdù.

Ago adj. / kọjá, sẹ́hìn.

Agonize verb. / jẹ̀rora.

Agony noun. / ìrora .

Agree verb. /  finúsọ̀kan, fohùnsọ̀kan, bárẹ.

Agreeable noun. /  yẹ, dára, jọjú, wọ̀.

Agreed adj. / gbígbà, nísọ̀kan, bíbárẹ́.

Agreement noun. / àdéhùn, ìfinú sọ̀kan, ìfọwọ́sowọ́.

Agricultural adj. /  nípa iṣẹ́ àgbẹ̀.

Agriculture noun. / oko ríro, iṣẹ́ àgbẹ̀, ìmọ̀ nípa ọ̀gbìn.

Agriculturist noun. / àgbẹ̀, aroko.

Ahead adv. / níwájú.

Aid verb. / ràn lọ́wọ́, tì lẹ́hìn.

Aid noun. / ìrànlọ́wọ́, ìtìlẹ́hìn.

Aide noun(f/m). / olùrànlọ́wọ́, olùtìlẹ́hìn.

Ailment noun. /  àìsan, àìlera, àrùn.

Aim noun. /  ohun àfojúsí, ohun tí à nwò níwájú.

Aim verb. /  wọ̀n wò , fẹ́, fojúsí.

Air

Air noun. /  òfúrufú, afẹ́fẹ́, ojú sánmọ̀.

Airless adj. /  àiláfẹ́fẹ́.

Airplane noun. /  bàlúù ọkọ̀ òfúrufú.

Airport noun. /  pápá bàlúù, pápá ọkọ̀ òfúrufú .

Airy adj. /  ní afẹ́fẹ́.

Akin adj. /  bátan nípa ìbí.

Alacrity noun. /  ìtúraká, ayára.

Alarm noun. /  ìdánijí, ìdágìrì.

Alarming adj. /  dìdánijí, dìdágìrì.

Albino noun. / àfín.

Album noun. /  ìwé ìfi àwòrán sí.

Alcohol noun. /  ohun tí npa ni nínú ọtí.

Alcoholic noun. /  ọ̀mùtí.

Alert adj. / ṣọ́ra, yára, dárayá.

Alias noun. /  orúkọ ìnágijẹ.

Alibi noun. /  ẹ̀rí àbò ìgbara ẹni là.

Alienate verb. / fi lé ẹlòmíràn lọ́wọ́, mú ìfẹ́ ẹni kúrò lọ́kàn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba