English - Yorùbá Dictionary

Ali

Alight verb. / sọ-kalẹ̀, ba lé.

Align verb. / ba dọ́gba, tò dọ́gba.

Alike adj. / jọra, bákannáà.

Alive adj. / yè, láàye.

All adj. /  gbogbo, olúkúlùkú.

Allay verb. /  wò sàn, mú fúyẹ́, fi balẹ̀.

Allegation noun. /  ìtẹ́numọ́,àwáwí,ẹ̀sùn.

Allege verb. /  tẹnumọ́, rò, so, sùn lẹ́sùn.

Allegiance noun. /  ìtẹríba, ìsin ọba.

Allergic adj. /  tí kò bálára mu.

Allergy noun. /  ohun àìbánilára mu.

Alley noun. /  ọ̀nà híhá, ọ̀nà tóóró.

Alliance noun. /  ìbáṣọ̀rẹ́ lárín orílẹ̀ èdè nípa májẹ̀mu, ìbátan nípa ìgbéyàwó.

Alligator noun. / ọ̀ni, alégbà.

Allocate verb. / fi sípò, pín fún.

Allocation noun. /  ìpín, ipò, ìfisípò.

Allot verb. /  pín, fífún.

Allow

Allow verb. /  gbà -fún,gbà-láyè.

Allowance noun. /  ohun tí a yọ̀da.

Alloy noun. /  àdàlù, ìbàjẹ́.

Allude verb. /  dasọ, tọ́ka sí .

Allure verb. /  tàn, fà-lọ, fà-láyà.

Ally noun. /  onígbèjà.

Almighty adj. /  olódùmarè,alágbára jùlo .

Almost adv. /  fẹ́re, kù diẹ̀,bù.

Alms noun. /  ọrẹ aanú,agbe.

Alms-man noun. / alágbe.

Alone adv. /  ohun nìkan.

Along prep. /  pẹ̀lú, lọ́dọ̀, lẹ́gbẹ̀ẹ́.

Aloud adv. /  kíkan, rara, sókè.

Already adj. /  nísìsìyí, síwájú àkọ́kọ́, ná.

Also adv. /  pẹ̀lú, gẹ́gẹ́, bẹ́ẹ̀.

Altar noun. /  pẹpẹ ìrúbọ.

Altar verb. /  yípadà, pàrọ̀,tún-ṣe.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba