English - Yorùbá Dictionary

Alt

Alteration noun. /  ìyípadà, ìpàrọ̀,àtúnṣe.

Alternative noun. /  yíyàn.

Although conj. / bí ó tilẹ̀jẹ́pé.

Altitude noun. /  gíga.

Altogether adv. /  pátápátá,gbogbo rẹ̀ .

Always adv. /  nígbà gbogbo, títí lái.

Amalgamate verb. /  dàpọ̀.

Amalgamation noun. /  ìdàpọ̀.

Amaze verb. /  yàlẹ́nu,ṣe hà.

Amazement noun. /  ìyanu, ìtagìrì.

Amazing adj. /  tìyanu.

Ambassador noun. /  ikọ̀ ìjọba, onṣẹ́ ìjọba.

Ambulance noun. /  ọkọ̀ aláìsàn.

Ambush noun. /  bíbá ní bùba.

Amen inter. /  àmín.

Amend verb. /  tún-ṣe.

Amendment verb. /  ìtúnṣe, àtúnṣe.

Amiable adj. /  ní inú rere.

Amicable

Amicable adj. /  bí ọ̀rẹ́, nílàjà.

Amis adj. /  aìtọ́, ṣíṣínà .

Ammunition noun. /  ohun ìjà.

Amnesty noun. /  ìdáríjì ìjọba fún àwọn ti o ṣẹ̀ ní ìlú .

Among prep. /  nínú, láàrín.

Amount noun. /  iye.

Ample adj. /  tóbi.

Amputate verb. /  gé kúrò nínú ara.

Amputation noun. /  ìgé kúrò nínú ara.

Amulet noun. /  óndè, ìgbádí, tírà .

Amuse verb. /  mú lárayá, bá ṣiré,pa lẹ́rín.

Amusement noun. /  ìmúlárayá,ìṣiré, ìdárayá .

An adj. /  ọ̀kan, kan.

Analysis noun. /  ìtú sí wẹ́wẹ́.

Ancestor noun. /  babanlá.

And conj. /  àti, sì.

Angel noun. /  ángẹlì, onṣẹ Ọlọ́run.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba