English - Yorùbá Dictionary

Neg

Negligent adj. /  onígbàgbé.

Negotiate verb. /  ṣe àdéhún, sọ ti ìṣòwò.

Negotiation noun. /  àdéhún, ìṣòwò.

Negro noun. /  ènìyàn dúdú.

Neigh noun. /  yíyán. verb. / yán bi ẹsin.

Neighbor noun. /  aládúgbò.

Neighborhood noun. /  àdúgbò ìlú, sàkani.

Neither pron. /  bẹ ni, kì.

Nerve noun. /  agbára ọgbọ́n.

Nervous adj. /  àìdá ara, ara gbígbọ̀n.

Nest noun. /  ìtẹ̀ ẹyẹ.

Net noun. /  àwọ̀n.

Never adv. /  bẹkọ láí.

New adj. /  titun, àkọtun.

News noun. /  ìròhìn, ìró, làbárè, ìgbúùró.

Newspaper noun. /  ìwè ìròhìn.

Next adj. /  èkejì. adv. / ẹlẹ́kejì, nítòsí.

Nice adj. /  dára, dùn, sunwọ̀n.

Niece

Niece noun. /  ọmọ arákùnrin arábìnrin ẹni tó jẹ́ obìnrin.

Night noun. /  òru.

Nightmare adj. /  àlá búburú, ìhanrun.

Nine noun. /  ẹsan, mẹsàn.

Ninth adj. /  ẹkẹsan.

Nipple noun. /  orí ọmú.

No noun. /  bẹ kọ, rárá. adj. / àgbẹdọ̀.

Nobody pron. /  ẹnì kankan, ènìyàn lásán.

Nod verb. /  mi orí sí.

Noise noun. /  ariwo.

Noisy adj. /  láriwo.

Nominate verb. /  pè lórúkọ, yàn, dárúko.

None pron. /  kò sí nkan.

Noon noun. /  ọ̀sán-gangan.

Normal adj. /  gẹ́gẹ́ bí ìlànà, gẹ́gẹ́ bí ìwọn.

North noun. /  àríwá, ìhá òkè.

Northern adj. /  ní àríwá, níha òkè.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba