HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Nor
Northwards
adv.
/ níha àríwá.
Nose
noun.
/ imú.
Nostrill
noun.
/ ihò imú.
Not
adv.
/ kò, kì.
Notable
adj.
/ níyìn, lókìkí, àfiyèsí.
Notary
noun.
/ alámì ìjẹri ìwé, ìjẹri sí ìwé.
Note
noun.
/ ìwé owó, àmì orin, ìwé kúkúrú.
verb.
/ kọ.
Notebook
noun.
/ ìwé ìfiyèsí, ìwé ìrántí.
Noteworthy
adj.
/ yẹ ni afiyèsí.
Nothing
adv.
/ àìsínkan, àìsí, àìwà, àìnílárí, ófo.
Notice
noun.
/ àfiyèsí, ìkìlọ̀, ìròhìn.
Noticeable
adj.
/ nífiyèsí.
Notification
noun.
/ ìkìlọ̀, ìfihàn.
Notify
verb.
/ sọ di mímọ̀, wí fún, kìlọ̀ fún.
Notion
noun.
/ ìmọ̀, irọ́.
Notorious
adj.
/ mímọ̀ ní gbangba, lókìkí.
Noun
noun.
/ orúkọ ènìyàn tàbí ti ohunkóhun.
Nourish
verb.
/ bọ, fi onjẹ fún, tọ dàgbà, kẹ.
Nov
Novel
noun.
/ ìwé ìtàn.
November
noun.
/ osù kọkànlá ọdún.
Now
adv.
/ ìgbà ìsisìyí, wàyí.
Nowhere
adv.
/ láìsíníbìkan.
Nozzle
noun.
/ imú, ẹnu.
Nude
adj.
/ níhòhò.
Nuisance
noun.
/ ìyọ́nu, ìrira, ìpanilára, ẹ̀gbin.
Number
noun.
/ iye.
Numerical
adj.
/ níye.
Nun
noun.
/ obínrin àlùfáà nínú ìjọ.
Nurse
noun.
/ olùtọ́, ọlójọ̀jọ̀ ọmọ, alágbàtọ́.
Nursery
noun.
/ ilé ìtọ́jú ọmọ wẹ́wẹ́.
Nursing home
noun.
/ ilé ìtọ́jú àwọn arúgbó.
Nursing
noun.
/ ìtọ́jú ìwòsàn.
Nurture
noun.
/ onjẹ, ẹ̀kọ́.
verb.
/ kọ́, tọ, bọ́.
Nut
noun.
/ kóró éso igi, èkùrọ́, ẹ̀pà.
Nutrition
noun.
/ onjẹ, bíbọ́, àjẹsára.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.