English - Yorùbá Dictionary

Oath

Oath noun. /  ìbúra, èpè.

Obedience noun. /  ìgbọ́ràn, ìforíbalẹ.

Obedient adj. /  nígbọràn, nítẹríba.

Obesity noun. /  ìsanra.

Obey verb. /  gbọ́ràn, tẹríba, gbàgbọ́.

Obituary noun. /  ìyìn ìsìnkú.

Object noun. /  ohun rírí. verb. / sòdì sí, kọ̀.

Objection noun. /  ìsodì sí, ìkọ̀.

Objective adj. /  láìní ojúsájú ènìyàn.

Obligation noun. /  ore, igbèsè ore, ọ̀ranyàn.

Oblige verb. /  ṣe ore, fi agbára mú ṣe.

Obliging adj. /  nínúrere, lójú anu.

Oblique verb. /  tẹ sí apákan.

Obliterate verb. /  pá rẹ́, pá run.

Obliteration noun. /  ìparẹ́, ìparun.

Obscene adj. /  láìnítìjú, nírira, èrí, ọbùn.

Obscenity noun. /  ohun ìtìjú, ìrira.

Obscure adj. /  ṣókùnkùn, farasìn.

Obs

Observant adj. /  wíwòye.

Observation noun. /  ìkíyèsí, ìfojúsí, gbólóhùn ọ̀rọ.

Observe verb. /  ṣe akíyèsí, fojúsí, sọ ọ̀rọ.

Observer noun. /  olùkíyèsí.

Obsolete adj. /  ti àtijọ́.

Obstacle noun. /  ohun ìdínà, ìdíwọ́.

Obstruct verb. /  dí lọ́nà, ìdíwọ́, dá dúró.

Obstruction noun. /  ìdílọ́nà.

Obtain verb. /  rí gbà, ní, gbà.

Obtainable adj. /  gbígbà, rírí gbà.

Obvious adj. /  láìsòro rí, híhàn gbangba, farahàn.

Obviously adv. /  láláìsòro rí, dájúdájú.

Occasion noun. /  àyè ọ̀nà, ìdí.

Occasionally adv. /  lẹkọkan, láìsègbàgbogbo, nílàre.

Occupation noun. /  iṣẹ́, ìní.

Occupy verb. /  gbé, ṣiṣẹ́, gba ipò.

Occur verb. /  ṣẹ̀, ṣẹlẹ̀, hàn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba