English - Yorùbá Dictionary

Occ

Occurence noun. /  ìṣẹ̀lẹ̀.

Ocean noun. /  òkun.

Octagon noun. /  onígun mẹ́jọ.

October noun. /  osù kẹ̀wá ọdún.

Octopus noun. /  ẹja ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́jọ.

Odd adj. /  láìbámu, pandan, láìgún gẹ́gẹ́.

Odds noun plural. /  nkan to ohun sẹlẹ̀, ànfàní, àisedédé.

Odour noun. /  òórùn.

Of prep. /  ti, níti, nípa.

Off adv. /  pa.

Offend verb. /  bà nínú jẹ.

Offense noun. /  ẹ̀ṣẹ̀.

Offensive adj. /  mú ìbàjẹ́ wá, kún fún òórún burúkú.

Offer noun. /  ẹbọ ìfilọ̀. verb. / fí fún, fi lọ̀.

Officer noun. /  ọ̀gágun.

Official noun. /  onísẹ́. adj. / lábẹ́ àṣẹ.

Often adv. /  nígbà kúgbà.

Old adj. /  ìdarúgbó, ìdàgbà, gbó, ìhewú.

Omega

Omega noun. /  opin.

Omit verb. /  fò kọjá, gbàgbé, fi sílẹ̀.

Omnipotence noun. /  agbára ailopin, ìwà ti Olodumare.

Omnipresent adj. /  ìwà ni ibi gbogbo ni àkókò kanna.

Omniscient adj. /  ọlọ́gbọ́n jùlọ, olùmọ̀ ohun gbogbo.

On adv. /  tàn sílẹ̀. prep / lórí.

Once adv. /  nígbà kan, lẹkàn, kan, ẹkan.

One noun. /  ọ̀kan, ení.

Onion noun. /  àlùbọ́sà.

Only adj. /  kan ṣoṣo, kan, péré. adv / nìkan, ọ̀kan ṣoṣo.

Open adj. /  gbangba, sísí, yíyà. verb. / sí sílẹ̀, yà.

Opening noun. /  ìsínú, ìsísílẹ̀, ìbẹ̀rẹ̀.

Openly adv. /  nígbangba, gedegbe, kedere.

Opera noun. /  eré onítàn olórin.

Operate verb. /  mú ṣiṣẹ́, ṣe iṣẹ́ abẹ fún.

Operation noun. /  iṣẹ́ abẹ, ìṣiṣẹ́.

Operator noun. /  oṣiṣẹ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba