English - Yorùbá Dictionary

Opi

Opinion noun. /  èrò.

Opponent noun. /  ọ̀tá, ataniláyà, alátàkò.

Opportunity noun. /  àyè, ọ̀nà, ìgbà, .

Oppose verb. /  ṣòdì sí, ṣe ìdènà, takò, dojú ìjà kọ.

Opposite adj. /  kọjú sí, dojúkọ. prep. / ọ̀kánkán.

Opposition noun. /  ìdènà, ìjiyàn, àtàkò, ìkọjúsí.

Oppress verb. /  ni lára, pọn-lójú, rẹ́ jẹ, dálóró.

Oppression noun. /  ìnilára, ìrẹ́jẹ, ìdálóró.

Optmism adj. /  ìgbàgbọ́ pé gbogbo nkan nsisẹ́ rere.

Option noun. /  ìyàn, ìwù, ìfẹ́.

Optional adj. /  wọ̀fún, yíyàn, èyí tí ó wu ni.

Or conj. /  tàbí, àbí.

Oral adj. /  ti ẹnu, fífẹnúṣọ.

Orange noun. /  ọsán.

Order noun. /  ìtò, ọjà rírà, àṣẹ ológun.

Ordinary adj. /  tí kì íse pàtàkì.

Ore noun. /  irin tútù.

Organize verb. /  tò lẹ́ṣẹṣẹ.

Ori

Oriental adj. /  ti ìlà òrùn.

Origin noun. /  ìpilẹ̀ṣẹ̀, ìbẹ̀rẹ̀, ìṣẹ̀dálẹ̀.

Original adj. /  àdáse, àbínibí, àtilẹ̀wá.

Originally adv. /  nípilẹṣẹ̀.

Orphan noun. /  ọmọ aláìlóbí.

Orphanage noun. /  ilé ìtọ́jú ọmọ aláìlóbí.

Ostrich noun. /  ògòngò.

Other adj. /  òmíràn, míràn.

Otherwise adv. /  bíkòse bẹ, bí bẹ kọ.

Our adj. /  ti wa.

Ourselves pron. /  àwa gangan.

Out adv. /  lóde.

Outcome noun. /  ìparísí, ìyọrísí, òpin.

Outdated adj. /  àìwúlò, ti ìgbà àtijọ́.

Outer adj. /  òde.

Outlook noun. /  ìṣọ́nà, ìwo iwájú, iwájú.

Output noun. /  ìmúwá, ìbísi.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba