English - Yorùbá Dictionary

Out

Outside prep. /  íta.adv. / lójúde, íta gbangba.

Outsider noun. /  ará òde, ará ìta, àjèjì.

Outskirt noun. /  agbègbè.

Outstanding adj. /  àìsan gbèsè lásìkò, títay ọ.

Outward adj. /  níha òde.

Over adv. /  lé. prep. / lórí, rékọjá, sórí, jùlọ, lé.

Overdue adj. /  rékọjá àkókò, pẹ.

Overflow verb. /  kún bò, kún kọjá, kún àkúnya.

Overload verb. /  di rékọjá.

Overlook verb. /  fojúfòdá.

Overnight adj. /  alẹ́ àná.

Overplus noun. /  èlé.

Overpower verb. /  borí, fi agbára tẹ̀, bò mọ́lẹ̀.

Overripe adj. /  pọ́n apọ́njù, pọ́n bàjẹ́.

Overrule verb. /  fi àṣẹ sí, pàṣẹ.

Overrun verb. /  parun, fọbàjẹ́.

Overseas adj. /  ìlú òkèrè.

Oversee verb. /  bojuto.

Ove

Overshadow verb. /  ṣíji bò.

Oversight noun. /  eṣi, ibojuto.

Oversleep verb. /  àsùnjù.

Overspread verb. /  tànká, gbilẹ̀.

Overtake verb. /  bá, lé bá, kọ já.

Overthrow verb. /  bì subú, yí dànù.

Overtime noun. /  ṣiṣẹ́ kọjá àsìkò, iṣẹ́ àṣerékọjá.

Overturn verb. /  yípadà.

Overweight noun. /  ìsanra àsansódì, ìwúwo jù.

Overwhelm verb. /  tẹ̀ mọ́lẹ̀, mu lómi, bò mọ́lẹ̀.

Owe verb. /  jẹ́ ní gbèsè.

Owl noun. /  òwìwí.

Own adj. /  tèmi. verb. / ní, gbà bí tẹni.

Owner noun. /  olóhun.

Ownership noun. /  onínkan, níní nkan.

Ox noun. /  màlú.

Oxygen noun. /  afẹ́fẹ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba