English - Yorùbá Dictionary

Pac

Pacific adj. /  parọ́rọ́, tutù.

Pacify verb. /  tù, rọ̀.

Pack verb. /  di ẹrù.

Package noun. /  ẹrù.

Packing noun. /  palẹ̀mọ́, ìdi ẹrù.

Pact noun. /  àdéhùn, ìmùlẹ̀.

Pad noun. /  ìrọ̀rí kékeré, òṣùká.

Paddle noun. /  ìwalẹ̀. verb. / ṣiré nínú omi.

Paddock noun. /  ọgbà àwọn ẹṣin.

Padlock noun. /  àgádágodo.

Pagan noun. /  kèfèrí, abọ̀rìṣà.

Page noun. /  ewé ìwé, ìránṣẹ́kùnrin.

Pail noun. /  korobá, peli.

Pain noun. /  ìrora, rírí.

Painful adj. /  dídun ni, níròjú.

Paint noun. /  ọ̀dà. verb. / fi ọ̀dà kùn.

Painter noun. /  akun ọ̀dà.

Pair noun. /  nkan méjì ti o bára wọn mu, awẹ́ méjì.

Pal

Palace noun. /  àfin, ilé ọba.

Pale adj. /  jíjorò.

Palm noun. /  àtẹ́lẹwọ́, ọ̀pẹ.

Palm tree noun. /  igi ọ̀pẹ.

Palm wine noun. /  ẹmu.

Pamper verb. /  kẹ, kẹra, jẹ àjẹkì.

Pan noun. /  páànù.

Panic noun. /  ìpààyà, ìdágìrì.

Pant verb. /  mí hẹlẹ.

Panther noun. /  àmọ̀tẹ́kùn, akátá.

Papa noun. /  bàbá.

Paper noun. /  ìwé, tákàdá.

Parade noun. /  ìtòlẹ́sẹ̀ ọmọ ogun, àṣehàn, ìfihàn.

Paradise noun. /  ọ̀run rere.

Paradox noun. /  ọ̀rọ̀ méjì tó se bí ẹnipé wọn yàtọ̀.

Paragon noun. /  àpẹrẹ oníwà pípé.

Paragraph noun. /  gbólóhùn ọ̀rọ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba