HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Qua
Quake
verb.
/ gbọ̀n, wariri, mì.
Quaking
adj.
/ gbígbọ̀n rìrì.
Qualification
noun.
/ ẹ̀rí, ìjẹri ìwà.
Qualify
verb.
/ múyé, yán.
Quality
noun.
/ ìwà, agbára, ìrí.
Qualm
noun.
/ aibalẹ̀ ẹ̀rí ọkàn.
Quandary
noun.
/ híhá sarin méjé, ìdàmú, ìsòro.
Quantity
noun.
/ títóbi, ìwọn, iye.
Quarantine
noun.
/ dídá ọkọ̀ dúró nítorí àisàn.
Quarrel
noun.
/ ìjà, asọ̀, gbólóhùn asọ̀.
verb.
/ jà.
Quarrelsome
adj.
/ tí ó lè jà, oníjà, aláriwo.
Quarry
noun.
/ ihò ibití atí nfọ́ òkúta.
Quart
noun.
/ ìdámẹ́rin òsùwọ̀n.
Quarter
noun.
/ ìdámẹ́rin ohunkóhun,.
Quash
verb.
/ tẹ̀ mọ́lẹ̀, ṣẹ́gun, paná.
Quaver
verb.
/ gbọ̀n lóhùn.
Quay
noun.
/ èbúté, ibi ìgúnlẹ̀ sí.
Queen
noun.
/ ayaba.
Que
Queer
adj.
/ yatọ, ṣòdi.
Quell
verb.
/ mú dakẹ, pa rẹ.
Quench
verb.
/ pa ku, párun.
Querulous
adj.
/ ainitẹlọrun, ráhùn, rojọ́.
Query
noun.
/ ìbérè.
verb.
/ ṣe ìbérè.
Quest
noun.
/ ìwákiri.
Queue
noun.
/ títò.
verb.
/ tò.
Quick
adj.
/ yára, láyè, tàrà, tètè.
Quickly
adv.
/ yárayára, nísìsìyí, kíákíá.
Quiet
adj.
/ dákẹ́, ìdákẹ́jẹ́, jẹ́jẹ́.
Quit
verb.
/ fi sílẹ̀, kọ sílẹ̀, lọ kúrò.
Quite
adv.
/ pátápátá.
Quiz
noun.
/ ìdánwò kúkúrú, ìbérè.
verb.
/ dánwò, se ìbérè.
Quota
noun.
/ ìpín.
Quotation
noun.
/ ọ̀rọ̀ gẹ́gẹ́ bi enití o ṣọ̀rọ̀ ti sọ́ gan.
Quote
verb.
/ ìdíyelé ọjà, tún ọ̀rọ̀ ẹlomi wi.
Quoth
verb.
/ wipe.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.