HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Rab
Rabbi
noun.
/ olùkọ́ni, olùkọ́ òfin ni èdè júù.
Rabbit
noun.
/ ehoro.
Rabble
noun.
/ ọ̀pọ̀ ènìyàn alainilari.
Rabid
adj.
/ ṣiwèrè.
Race
noun.
/ eré ìje, iré sísá, ìran, ẹ̀yà.
verb.
/ sá, sáré.
Racetrack
noun.
/ gbàngbà ìsúré ìjé.
Racism
noun.
/ ìwà ìkórira.
Racist
noun.
/ akórira ẹlòmíràn.
Radiance
noun.
/ ìtànmọ́lẹ̀, itanṣan.
Radiant
adj.
/ títànsán.
Rag
noun.
/ àkísà.
Rage
noun.
/ ìrunú, ìbínú.
Raid
verb.
/ gbógun tì, rọlù.
noun.
/ ìgbógun tì.
Rail
noun.
/ ọgbà irin tàbí igi ojú irin rélùwé.
Rain
noun.
/ òjò.
Rainbow
noun.
/ òṣùmàrè.
Raise
noun.
/ ìbùsí iye owó.
verb.
/ gbé sókè, gbé dúró.
Ram
noun.
/ àgbò, ràgò.
Ram
Ramadan
noun.
/ oṣu awẹ mùsùlùmí.
Ramble
noun.
/ irin kakiri.
Random
adj.
/ alábàpàdé, láìròtẹ́lẹ̀.
Range
noun.
/ gígùn, ìnà, òkè gíga, iyeorísi.
Rank
noun.
/ ẹgbẹ́, ipò.
Ransom
noun.
/ ìràpadà, owó ìdásílẹ̀, ìràsílẹ̀, ìgbàsílẹ̀.
Rape
noun.
/ ìbálò obìnrin nítipá tàbí dandan.
Rapid
adj.
/ yára, kánkán.
Rapture
noun.
/ ayọ púpọ̀, ayọ àyọ̀jù.
Rare
adj.
/ sọ̀wọ́n, aìpọ̀.
Rash
noun.
/ èsú ara, sísú.
Rat
noun.
/ èkúté.
Rate
noun.
/ iye, òṣùwọ̀n.
Rather
adv.
/ kúkú, sànjù, bókànràn.
Ratify
verb.
/ pinnu, fi ohùn sí.
Ration
noun.
/ ónjẹ ò jọ àwọn ọmọ ogun.
Rational
adj.
/ ní iyè nìnú, lọ́gbọ́n nìnú.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.