HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Res
Resign
verb.
/ fi sílẹ̀, fi lé lọ́wọ́, síwọ́ iṣẹ́.
Resignation
noun.
/ ìfisílẹ̀, ìjọ́ lọ́wọ́.
Resist
verb.
/ kọjú ìjà sí, tàpá sí, takò.
Resistance
noun.
/ ìkọjújàsí, ìtàpásí, ìtakò.
Resolve
verb.
/ se àtúnse, pinnu.
Respect
noun.
/ àpónlé, ọ̀wọ̀, ìyìn.
Respectful
adj.
/ kún fún ọ̀wọ̀, tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀.
Respond
verb.
/ dá hùn, fèsì.
Response
noun.
/ ìdáhùn, èsì.
Rest
noun.
/ ìsimi, oorun ìdákẹ́.
Restless
adj.
/ láìnísimi.
Restoration
noun.
/ ìmúpadà sípò.
Restore
verb.
/ mú padà sípò, mu bọ sípò.
Restrict
verb.
/ pàlà fún, há mọ, fi mọ.
Restriction
noun.
/ ìpàlà, ìhámọ́, àlà.
Result
noun.
/ ìparí, ìyọrísí, òpin, èsì.
Resume
verb.
/ tún bẹ̀rẹ̀.
Retain
verb.
/ dá dúró.
Ret
Retake
verb.
/ tún mú, tún gbà.
Retaliation
noun.
/ ìgbẹ̀san.
Retention
noun.
/ ìdádúró, ìdílọ́wọ́, ìpamọ́.
Retire
verb.
/ lọ simi, ṣiwọ́ iṣẹ́.
Retract
verb.
/ yí ọ̀rọ̀ padà.
Retrain
verb.
/ tún kọ.
Retrieve
verb.
/ gbà padà.
Retrogress
adj.
/ ọlá nrẹyin.
Return
noun.
/ ìpadà, ìtúndé, àbọ̀.
verb.
/ bọ̀, túndé, padà.
Reunion
noun.
/ ìpàdé lẹ́hìn ìpínyà.
Reuse
verb.
/ tún lò.
Reveal
verb.
/ ṣípaya, fihàn, ṣí sílẹ̀.
Revel
noun.
/ àríyá.
Revelation
noun.
/ ìfihàn, ìsípaya.
Revenge
noun.
/ ìgbẹ̀san.
Reverse
noun.
/ yi pada, parọ
Revert
verb.
/ padà sí, lé padà.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.