English - Yorùbá Dictionary

Rev

Review verb. /  tún wò, fi ẹ̀sọ wò, yẹwo.

Revise verb. /  wò fún àtúnse.

Revision noun. /  ìtúnwò.

Revive verb. /  mú sọjí, mú yè, jí dìde, tún gbé dìde.

Revoke verb. /  pe padà, mu kúrò, gbà padà, párẹ́.

Revolt noun. /  ọ̀tẹ̀. verb. / ṣọ̀tẹ̀.

Revolution noun. /  iṣọ̀tẹ̀, ìyíká.

Revolve verb. /  yíká.

Reward noun. /  èrè, ẹ̀bùn, ẹsan.

Rewind verb. /  tún ká, tún wé.

Rewrite verb. /  tún kọ.

Rib noun. /  egungun ihà, egungun àyà.

Rich adj. /  ọlọ́rọ̀, ọlọ́ra, olówó.

Ride noun. /  gígùn. verb. / gùn ẹṣin, gùn.

Redge noun. /  òké òrùlé, òté íle.

Ridiculous adj. /  laimu ọgbọ́n wa, kò sí ọgbọ́n.

Right adj. /  tó yẹ, dára, ọ̀tún.

Righteous adj. /  lòdodo, lótìtọ́, aláre.

Rig

Rigid adj. /  le, sòro láti se.

Rigidly adv. /  pẹ̀lú ìsòro, líle.

Rigor noun. /  gbígbọ̀n.

Rigour noun. /  ìsòro.

Rill noun. /  odò ṣísàn kékeré.

Rim noun. /  etí, bèbè.

Ring noun. /  òrùka. verb. / lù bí agogo, ró bí agogo.

Rinse verb. /  fi omi sàn.

Riot noun. /  ìrúkèrúdò, ariwo ija.

Rip noun. /  ìlà. verb. / fà ya, là.

Ripe adj. /  pọ́n.

Rise verb. /  dìde, gòkè, jínde, là.

Risk noun. /  ewu.

Risky adj. /  léwu.

River noun. /  odò.

Road noun. /  ọ̀nà.

Roast verb. /  sun, yan, dín, gbẹ.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba