English - Yorùbá Dictionary

Rob

Rob verb. /  jalè, jà lolè, jí.

Robbery noun. /  olè jíjà.

Rock noun. /  àpáta, òkúta nlá.

Rocky adj. /  kún fún òkúta.

Roll verb. /  yí, ká.

Roof noun. /  òrùlé.

Room noun. /  yàrá, àyè.

Roomy adj. /  tí ó ní àyé.

Root noun. /  gbòngbò, ìpilẹ̀sẹ̀.

Rope noun. /  okùn.

Rosary noun. /  tẹ̀súnbà.

Rose noun. /  òdòdó olórùn, dìde, gòkè.

Rot noun. /  ìbàjẹ́, rírà.

Rotate verb. /  yí bí kẹ̀kẹ́.

Rotten adj. /  dìbàjẹ́, rà.

Rough adj. /  sàìdán.

Route noun. /  ìpa ọ̀nà.

Routine noun. /  nkan ti a nse ni ojojúmọ́ tó jẹ́ bákan ná.

Row

Row noun. /  ìlà.

Royal adj. /  ti ọba, bí ọba.

Rub verb. /  gbo, pa, fi ra, fi pa.

Rubbish noun. /  pàntí, ohun aláìnílárí.

Rude adj. /  láìmoye, aláìmọwàhù, láìnibọ̀wọ̀ fún.

Rule noun. /  òfin. verb. / fa ìlà.

Ruler noun. /  alákoso, igi fún fífa ilà.

Rumor noun. /  àgbọṣọ ọ̀rọ̀ ti o le jẹ̀ irọ́ tàbí òtító.

Rump noun. /  ìdí, ìparí ẹ̀yin.

Run noun. /  eré. verb. / sá ré, du, súré.

Runner noun. /  ẹnití nsare.

Rupture noun. /  ìyapa, kùn sínú.

Rural adj. /  ti oko, ti igbó, ibití o jìnà silu.

Ruse noun. /  ìsújú, èrú, eré ẹ̀tan.

Rush verb. /  kánjú, bíbò nkan.

Rust noun. /  ìdógun.

Ruthless adj. /  láìlánú, níkà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba