English - Yorùbá Dictionary

Sab

Sabbath noun. /  ọjọ́ sátidé fún àwon juu, ọjọ́ isimin.

Sabotage noun. /  ìjìn lẹ́sẹ̀, bíba ohun ẹlòmíràn jẹ́.

Sack noun. /  àpò nlà, yọ. verb. / yọ kúrò.

Sacrament noun. /  ìmùlẹ̀, ìbúra.

Sacred adj. /  ìgbàgbọ́ pe o mọ́, mímọ́.

Sacrifice noun. /  ẹbọ. verb. / rúbọ, fi sílẹ̀.

Sad adj. /  banújẹ́, fajúro.

Sadness noun. /  ìbànújẹ́.

Safe adj. /  láìléwu.

Safety noun. /  ibi àìléwu.

Sag verb. /  yẹ̀ gẹ̀rẹ̀.

Sage noun. /  ọlọ́gbọ́n, amòye.

Said verb. /  wí, sọ.

Saint noun. /  ènìyàn mímọ́.

Sake noun. /  ìtorí.

Salary noun. /  owó osù.

Sale noun. /  ìta ọjà, gbànjo.

Saliva adj. /  itọ́ ẹnu.

Sal

Salt noun. /  iyọ̀.

Salty adj. /  tí iyọ̀ já, oníyọ̀.

Salutation noun. /  ìkí, ìkíni.

Salute verb. /  kí.

Salvation noun. /  ìgbàlà.

Same adj. /  ìkannà, bakanna.

Sample noun. /  àpéjúwe, àpẹrẹ.

Sand noun. /  yanrìn.

Sanitation noun. /  ètò ìmọ́tótó.

Sarcastic adj. /  pẹ̀lú ẹ̀gàn.

Satisfaction noun. /  ìtẹ́l ọ́rùn.

Satisfactory adj. /  nítẹ̀lọ́rùn, tí ó kúnni lójú.

Satisfy verb. /  tẹ̀ lọ́rùn, kún lójú.

Saturday noun. /  ọjọ́ àbámẹ́ta, ọjọ́ kẹfà ọsẹ.

Sauce noun. /  ọbẹ̀.

Savage adj. /  níkà, rorò.

Save verb. /  fi pamọ́, yọ nínú ewu.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba