English - Yorùbá Dictionary

Sav

Saving noun. /  ìfowópamọ́.

Saw noun. /  ayùn. verb. / rẹ́ igi, yùn, rí.

Say verb. /  wí, sọ.

Saying noun. /  wíwí, sísọ, ọ̀rọ̀ sísọ.

Scab noun. /  èpo, èpá.

Scaffold noun. /  àkàsọ̀, àtẹ̀gùn.

Scald noun. /  nkan gbígbóná jó ẹ, dà jó.

Scan verb. /  wadi.

Scandal noun. /  ohun ìkọsẹ̀, ẹ̀gàn, àbùkù, ìsọkúsọ.

Scar noun. /  ojú àpá, àpá egbò.

Scarce adj. /  ṣọ̀wọ́n, wọ́n, àìtó.

Scare noun. /  ìdẹ́rùbà. verb. / dẹ́rùbà.

Sarf noun. /  aṣọ pénpé tí a fi nbo ọrùn.

Scatter verb. /  fánká, túká.

Scenery noun. /  ìrí ilẹ̀ yíká, ìwo ilẹ̀.

Sceptical adj. /  oníyèméjì.

Schedule noun. /  lanà, èrò, ìmò.

Schism noun. /  ìyapa.

Sch

Scholar noun. /  ọlọ́gbọ́n, akẹkọ.

Scholarship noun. /  ànfàní láti kọ́ ìwé lọfẹ.

School noun. /  ilé ìwé, ilé ẹ̀kọ́.

Scold verb. /  báwí, bá sọ.

Scorpion noun. /  àkekèé.

Scrape verb. /  ha ojú nkan.

Scratch verb. /  họ, ya, yún, ya ni nkan.

Scream noun. /  igbe híhan. verb. / han, kígbe, ké.

Screw noun. /  ìdè. verb. / dè.

Scribble verb. /  kọ sílẹ̀.

Script noun. /  ìwé àfọwọ́kọ.

Scrub verb. /  fọ, gbo.

Sculpture noun. /  ère gbígbẹ́.

Sea noun. /  òkun.

Seal verb. /  lẹ̀.

Seam noun. /  etí aṣọ.

Search noun. /  ìwádì, àwárí. verb. / se ìwárí, wádí, wákiri.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba