English - Yorùbá Dictionary

Sea

Seashore noun. /  etí odò.

Season noun. /  ìgbà.

Seasonal adj. /  ti ìgbà.

Seasoning noun. /  ohun tí a fi sínú onjẹ láti mú kí ó dùn.

Seat noun. /  ìjókò.

Second adj. /  èjì, èkejì.

Second noun. /  ìsẹ́jú.

Secondary adj. /  ti èkejì, èyítí ó tẹ̀lé.

Secondly adv. /  ni ọ̀nà kejì.

Secrecy noun. /  ìkọ̀kọ̀, àṣírí.

Secret noun. /  ohun ìkọ̀kọ̀. adj. / nìkọ̀kọ̀, làṣírí.

Secretary noun. /  akọ̀wé.

Secretly adv. /  nìkọ̀kọ̀, bònkẹ́lẹ́, l'aṣiri.

Sect noun. /  ẹgbẹ́, ìyàpà ìsìn, alá, damọ̀.

Section noun. /  apákàn, ìpín.

Secure adj. /  láìléwu.

Security noun. /  àbò, onígbọ̀wọ́.

Sedate verb. /  dákẹ́, bíbàlẹ̀, laipariwo.

Sed

Sediment noun. /  pọ̀tọ̀pọ́tọ̀, ẹrọ̀fọ̀.

Seduce verb. /  wù láti báse, bà jẹ.

See verb. /  rí, fojú rí, ríran.

Seed noun. /  irúgbìn, irúmọ.

Seek verb. /  wá, wá kiri, bèrè.

Seem verb. /  ṣe bí ẹnipé, ṣe àfihàn.

Seemly adj. /  yẹ, tọ́, dára.

Seer noun. /  aríran, wòli.

Segment noun. /  ìkékúrò, ìrépé.

Segregate verb. /  ya ara sọ́tọ̀, fi àlà sí.

Segregation noun. /  iya ara sọ́tọ̀, ifi àlà sí.

Seize verb. /  fi agbára gbà, gbá, mú ní tipá.

Select verb. /  ṣàyàn.

Selection noun. /  ìṣàyàn.

Self adj. /  ẹni, tìkara ẹni.

Selfish adj. /  tí ó mọ ti ara rẹ nìkan.

Selfishness noun. /  ìwa ìmọ́ ti ara ẹni nìkan.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba