English - Yorùbá Dictionary

Tel

Tell verb. /  wí fún, sọ fún.

Temper noun. /  ìbínú, ìrunúi.

Temperament noun. /  ìwà inú.

Temple noun. /  ilé ìsìn Ọlọ́run tàbí òrìsà.

Temporary adj. /  wíwà fún ìgbá díẹ.

Tempt verb. /  dán wò, tán ṣe búburú.

Temptation noun. /  ìdánwò, ẹ̀tàn.

Tempting adj. /  títan ni, wíwu ni, dídán niwò.

Ten (10) noun. /  ẹwá, mẹwá.

Tenable adj. /  ti a lè gbà, ti a lè dìmú.

Tenant noun. /  ayálé gbé, ará ilé.

Tendency noun. /  ìtẹ̀sí, ipa, ọ̀nà, ìtọ́ka sí.

Tender verb. /  nawọ́ si, fi fun.

Tenderly adv. /  pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, jẹ́jẹ́.

Tendon noun. /  isan ara.

Tense noun. /  ìgbà tàbí àkókò tí a ṣe nkan.

Term noun. /  ọ̀rọ̀, àlà, ìpínlẹ̀, òpin, àkókò.

Terminate verb. /  pinnu, parí, fòpin sí, yọ kúrò nínú iṣẹ́.

Ter

Termination noun. /  òpin, ìfòpinsí, ìdádúró lẹ́nu iṣẹ́.

Termite noun. /  ikán.

Terrace noun. /  ibi ìtẹ̀jú ilé.

Terrible adj. /  lẹ́rù, banilẹ́rù.

Terribly adv. /  níbanilẹ́rù.

Territory noun. /  ilẹ̀, agbègbè ìlú.

Terror noun. /  ẹrù, ìpáyà, ìjáyà.

Test noun. /  ìdánwò. verb. / dán wò.

Testament noun. /  ìwé májẹ̀mu.

Testicle noun. /  kóró ẹpọ̀n, ẹpọ̀n.

Testify verb. /  ṣe ijẹri, jẹri si.

Testimonial noun. /  ìwé ijẹri.

Testimony noun. /  ẹri, ijẹri.

Textbook noun. /  ìwé ẹ̀kọ́ kíkà.

Than conj. /  ju ti, ju ki, ju pé.

Thank verb. /  dúpẹ́, ṣọpẹ́.

Thankful adj. /  kún fún ọpẹ́.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba