English - Yorùbá Dictionary

Tha

Thanks noun. /  ìdúpẹ́, ọpẹ́.

THanksgiving noun. /  ìfi ọpẹ́ fun.

That pron. /  èyí, èyítí, ohun tí.

The adj. /  na.

Theatre noun. /  gbọ̀ngàn eré.

Theft noun. /  olè jíjà.

Their pron. /  ti wọn, wọn.

Them pron. /  àwọn, wọn.

Theme noun. /  ọ̀rọ̀ ìpìlẹ̀, gbòngbò ọ̀rọ̀ ṣíṣọ.

Themselves pron. /  àwọn tìkarawọn, àwọn na.

Then adv. /  nígbàna, lakoko na, nigbana, njẹ.

Thence adv. /  láti ibẹ̀ lọ, láti ibẹ̀ wà.

Theologian noun. /  ọlọ́gbọ́n nínú kíka ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Theology noun. /  imọ Ọlọ́run.

Theory noun. /  ìdámọràn ohun èrò.

There adv. /  níbẹ̀ na, lọhun, nibẹ.

Thereafter adv. /  lẹ́yìnna, nítẹ̀lé.

Thereby adv. /  nípa èyí na.

The

Therefore adv. /  nítorína, nítorí èyí na.

Therein adv. /  nínú èyí na.

Thereof adv. /  ti inú èyí na.

Thereon adv. /  lórí èyí na.

These pron. /  ìwọ̀nyí, àwọn wònyí.

They pron. /  àwọn.

Thick adj. /  nípọn.

Thickness noun. /  nínípọn.

Thief noun. /  olè, ajínilóhun, jàgùdà, ìgárá.

Thing noun. /  ohun, nkan.

Think verb. /  rò, ronú, wòye.

Third adj. /  ẹkẹta, kẹta.

Thirdly adv. /  lọ́nà kẹta.

Thirst noun. /  òrùngbẹ, òngbẹ.

Thirsty adj. /  pongbẹ.

Thirty (30) noun. /  ọgbọ̀n.

This adj. /  eléyí, èyí.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba