English - Yorùbá Dictionary

Uns

Unsatisfied adj. /  láini ìtẹ́lọ́rùn.

Unscriptural adj. /  lodi si ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Unsearchable adj. /  láileṣe àwárí.

Unsettled adj. /  láidúró nibi kan.

Unskilful adj. /  láilọ́gbọ́n, láinímọ̀.

Unsociable adj. /  láikẹ́gbẹ́, tí kò túraká sí ènìyàn.

Unstable adj. /  láifi ẹsẹ̀ múlẹ̀.

Unsuccessful adj. /  láiyege.

Unsuitable adj. /  làilyẹ, láibámu .

Unsure adj. /  láidánilójú.

Unthinkable adj. /  láisérò.

Untidy adj. /  wúru wùru.

Untie verb. /  tú.

Until prep. /  títí dìgbà.

Untimely adj. /  láisàkókò, láitò àkókò.

Unto prep. /  sí, sí ọdọ.

Untouched adj. /  láifọwọ́ bà.

Untranslated adj. /  láiyípadà si èdè mí.

Unt

Untried adj. /  láidanwò.

Untrue adj. /  irọ́.

Unused adj. /  tí a kò ìtí lò, láilò.

Unusual adj. /  láiṣe nígbàkúgbà.

Unveil verb. /  ṣi níbòjú.

Unwarned adj. /  láikilọ fún.

Unwashed adj. /  láifọ.

Unwelcome adj. /  láifi ayọ̀ gbà.

Unwell adj. /  ṣaisan.

Unwilling adj. /  láini ìfẹ́.

Unwritten adj. /  tí a ko kọ sílẹ̀.

Up adv. /  sókè, lókè. prep / lórí.

Upon prep. /  lórí, sórí.

Uprising noun. /  àìsimi ìlú.

Us pron. /  wa.

User noun. /  ẹnití nlo nkan.

Usually adv. /  àtẹ̀hínwà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba