English - Yorùbá Dictionary

War

Warrant noun. /  ìwé àṣẹ ìmúni.

Warranty noun. /  ìwé ìdánilójú láti pàrọ̀ tàbí túnse.

Warrior noun. /  jagunjagun, ọ̀gájun, ológun.

Wary adj. /  niṣọra, niṣọna, níwòye.

Was verb. /  wà, jẹ́, ni.

Wash noun. /  ìwẹ̀, fífọ̀. verb. / wẹ̀, fọ̀ bọ́.

Washman noun. /  alágbàfọ̀ ọkùnrin.

Waste noun. /  ahoro, ìdáhoro, ìparun. verb. / jẹrun.

Wasteful adj. /  ìnádànù, ìnákúnà, yà pà.

Wasting adj. /  nibajẹ, ni iparun.

Watch noun. /  ẹ̀ṣọ́, ìṣọ́, agogo, ago. verb. / ṣọ́, wò ran.

Watchful adj. /  níṣọra, ṣíṣọ́, tí ó fojúsílẹ̀.

Watchman noun. /  olùṣọ, ẹṣọ, ọdẹ.

Water noun. /  omi. verb. / fún ní omi, bo mi wọn.

Water barrel noun. /  agbá omi.

Water bottle noun. /  igò omi.

Waterfall noun. /  ọ̀sọ̀rọ̀ òjò, ìtàkìtì omi.

Watermelon noun. /  èso bàrà.

Wat

Watery adj. /  rin, gbindin.

Wave noun. /  ìjuwọ́, rúrú omi òkun. verb. / juwọ́ sí.

Way noun. /  ọ̀nà, ojú ọ̀nà.

Wayward adj. /  níwàkuwà, ṣaigbọran, ṣagídí.

We pron. /  àwa.

Weak adj. /  láilágbára, aláilera, aláisàn, lailokun.

Weaken verb. /  mú rọ, sọ di àilera, sọ di aláilágbára.

Wealth noun. /  ọrọ̀, ọlá, owó tó pọ̀.

Wealthy adj. /  lówó, lọ́rọ̀, ọlọ́rọ̀, lọ́lá.

Weapon noun. /  ohun ìjà, ohun ogun, ohun ílò.

Wear verb. /  wọ̀, lò.

Weather noun. /  ojú ọjọ́, ojú ọ̀run.

Weave verb. /  hun, wun, wunsọ, wun okùn.

Web noun. /  ìtakùn, okun alantakun.

Wedding noun. /  ìgbéyàwó, ìsoyigi.

Wedding day noun. /  ọjọ́ ìgbéyàwó.

Wedding ring noun. /  òrùka ìgbéyàwó.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba