English - Yorùbá Dictionary

Wed

Wednesday noun. /  ọjọ́ kẹrin ọsẹ, ọjọ́rú.

Wee adj. /  kékeré.

Weed noun. /  koriko, èpo.

Weedy adj. /  kún fún èpo.

Week noun. /  ọsẹ kan, ọjọ́ méje.

Weekend noun. /  ìparí ọsẹ.

Weekly adj. /  lọ́sọ̀sẹ̀, lẹkan lọ́sọ̀sẹ̀,.

Weep verb. /  ké, sọkún, damijé.

Weight verb. /  wọn, gbé wò, rẹ̀sílẹ̀. noun. / iwọn, ìwúwo.

Weighty adj. /  wúwo, lágbára.

Weird adj. /  ṣabàmì, ṣàjèjì.

Welcome noun. /  ìkíni, àríyọ̀, ìkí ayọ̀ fún àlejò. adj. kabọ

Weld verb. /  jó irin pọ̀.

Welfare noun. /  alafia ènìyàn, ìrànlọ́wọ́ ìjọba fún ará ìlú.

Well noun. /  kanga, orísun omi. adv. / lálàfíà, ní dídá ara.

Well behaved adj. /  ní ìwà rere.

Well done inter. /  o ṣé dada.

Went verb. /  ti lọ.

Wes

West noun. /  ìwọ òrún.

Western adj. /  níhà ìwọ òrùn.

Wet adj. /  rin, tutù.

Wether noun. /  ẹran ti a tẹ lọda, ọ̀dá àgbo.

Whack verb. /  fi agbára lù.

Wharf noun. /  èbúté.

What pron. /  kíni, kínlá, èwo. verb. / kíni o wí.

Whatever pron. /  ohunkóhun, èyíkéyì, èyíwù kóse.

Wheeze verb. /  mí kankan.

When conj. /  ìgbàtí. adv. / nígbàtí, nígbàwo.

Whence adv. /  láti ibẹ̀ wà, láti ibo.

Whenever adv. /  nígbàkúgbà, nígbà tí ó wù ki o ṣe.

Where adv. /  ibo, níbo, níbití.

Wherever adv. /  ibikíbi, níbikíbi.

Which pron. /  èwo, èyítí. adj. / tí èyítí.

While noun. /  ìgbà àkókò. adv. / nìwọn bí, nígbàtí.

Whine noun. /  híhú, kíkùn. verb. / hú, ké, kùn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba