English - Yorùbá Dictionary

Whi

Whip noun. /  ọrẹ́, pàsán, ẹgba. verb. / lú, ná lẹ́gba.

Whisker noun. /  irun imú olóngìnní.

Whisper verb. /  ọ̀rọ̀ jẹ́jẹ́, ọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́, òfófó.

Whistle noun. /  ìsúfé, fèrè. verb. / súfé, fọn fèrè.

White noun. /  funfun.

Who pron. /  tani, ẹnití.

Whoever pron. /  ẹnikẹ́ni.

Whole adj. /  lódidi, ní dídá ara. noun. / gbogbo.

Wholesale adj. /  ìtajà ní odidi.

Wholesome adj. /  dára fun ara, dára ní jíjẹ.

Whom pron. /  ẹnití.

Whomsoever pron. /  ẹnikẹ́ni.

Whore noun. /  àgbèrè, asẹ́wó, ọ̀dọ́kọ.

Whoredom noun. /  ìwà àgbèrè.

Whose pron. /  ti tani, ti ẹnití.

Why adv. /  eese, etise, nítorí kíni, kílóse, kíni ìdirẹ̀, é tírí.

Wick noun. /  òwú ìtanná, òwú fìtílà.

Wicked adj. /  búburú, burú, àilánú, ìwà ìkà.

Wid

Wide adj. /  gbòrò, jìnnà.

Widen verb. /  fẹ̀, fẹ̀ níbù, sí sílẹ̀.

Widespread adj. /  ìtànkálẹ̀, ìtànká.

Widow noun. /  opó obìnrin.

Widower noun. /  opó ọkùnrin.

Width noun. /  ìbú.

Wife noun. /  ìyàwó, aya.

Wig noun. /  irun atọwọda.

Wiggle verb. /  rúnra, mira.

Wild animal noun. /  ẹranko ìgbẹ́.

Wilderness noun. /  aginjù, ìgbẹ́, ijù.

Wilful adj. /  mọ mọ se, tí o ṣe pẹ̀lú ìfẹ́ inú.

Will noun. /  ìfẹ́, ìwù, ìwé ìpín ogún.

Willing adj. /  ní ìfẹ́ sí, fífẹ́.

Willingly adv. /  tìfẹ́tìfẹ́, tinútinú.

Willingness noun. /  ìfẹ́, ìfẹ́ inú.

Wimp noun. /  ẹnití kò láyà, kò lọ́kàn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba