HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Win
Win
verb.
/ ṣẹ́gun, borí, jẹ, gbà.
noun.
/ ìsẹ́gun.
Winch
noun.
/ ẹ̀rọ ìgbé ẹrù wíwo sókè.
Wind
noun.
/ afẹ́fẹ́, ẹ̀fúfú.
verb.
/ yika, ká, káwé.
Window
noun.
/ fèrèsé, ojú afẹ́fẹ́.
Windscreen
noun.
/ fèrèsé ojú ọkọ̀.
Windshield
noun.
/ fèrèsé ojú ọkọ̀.
Windy
adj.
/ ti afẹ́fẹ́, kìkì afẹ́fẹ́, ní afẹ́fẹ́.
Wing
noun.
/ ìyẹ́ apá, apá ọkọ̀ òfúrufú.
Wink
verb.
/ ṣẹ́jú, dijú bàibàì, ìfojúparẹ́.
Winner
noun.
/ asẹ́gun.
Winter
noun.
/ ìgbà òtútù.
Wipe
verb.
/ nù, nùkúrò.
Wire
noun.
/ okùn onírin.
Wisdom
noun.
/ ọgbọ́n, òye, ìmọ̀.
Wise
adj.
/ gbọn, mòye, mọ̀.
Wish
noun.
/ ìfẹ́, ìwù.
verb.
/ fẹ́.
Witch
noun.
/ àjẹ́.
Witchcraft
noun.
/ isẹ àjẹ́.
With
With
prep.
/ pẹ̀lú, àti, lọ́dọ̀, bá, fi, dání.
Withdraw
verb.
/ fà padà, gbà padà, yọ́ kúrò.
Within
adv.
/ nínú, ti inú.
Without
prep.
/ lóde, lẹ́hìn òde, láisí.
Withstand
verb.
/ dúrótì, kọju ìjà sí, dí lọ́nà, dojúkọ́.
Witness
noun.
/ ẹ̀rí, ẹlẹ́rí.
verb.
/ jẹri, ṣẹlẹ́rí.
Wolf
noun.
/ ìkokò.
Woman
noun.
/ obìnrin.
Womb
noun.
/ ibití ọmọ ma dúró si nínú obìnrin.
Wonder
noun.
/ ìyanu, isẹ́ ìyanu, èmọ̀, kísà.
Wonderful
adj.
/ yanilẹ́nu, kún fún ìyanu, níyànjú.
Wood
noun.
/ igi fún ilé kíkọ́.
Wooden
adj.
/ onígi.
Wool
noun.
/ irun àgùtàn, òwú.
Word
noun.
/ ọ̀rọ̀, gbólóhùn kan.
Work
noun.
/ iṣẹ́.
Workable
adj.
/ tí ó sesẹ́.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.